Quran with Yoruba translation - Surah Ya-Sin ayat 21 - يسٓ - Page - Juz 23
﴿ٱتَّبِعُواْ مَن لَّا يَسۡـَٔلُكُمۡ أَجۡرٗا وَهُم مُّهۡتَدُونَ ﴾
[يسٓ: 21]
﴿اتبعوا من لا يسألكم أجرا وهم مهتدون﴾ [يسٓ: 21]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ẹ tẹ̀lé ẹni tí kò bèèrè owó-ọ̀yà kan ní ọwọ́ yín. Olùmọ̀nà sì ni wọ́n |