Quran with Yoruba translation - Surah Ya-Sin ayat 22 - يسٓ - Page - Juz 23
﴿وَمَالِيَ لَآ أَعۡبُدُ ٱلَّذِي فَطَرَنِي وَإِلَيۡهِ تُرۡجَعُونَ ﴾
[يسٓ: 22]
﴿وما لي لا أعبد الذي فطرني وإليه ترجعون﴾ [يسٓ: 22]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Kí ni ó máa mú mi tí èmi kò fi níí jọ́sìn fún Ẹni tí Ó pilẹ̀ ẹ̀dá mi? Ọ̀dọ̀ Rẹ̀ sì ni wọn yóò da yín padà sí |