Quran with Yoruba translation - Surah Ya-Sin ayat 46 - يسٓ - Page - Juz 23
﴿وَمَا تَأۡتِيهِم مِّنۡ ءَايَةٖ مِّنۡ ءَايَٰتِ رَبِّهِمۡ إِلَّا كَانُواْ عَنۡهَا مُعۡرِضِينَ ﴾
[يسٓ: 46]
﴿وما تأتيهم من آية من آيات ربهم إلا كانوا عنها معرضين﴾ [يسٓ: 46]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àti pé āyah kan nínú àwọn āyah Olúwa wọn kò níí wá bá wọn àfi kí wọ́n máa gbúnrí kúrò níbẹ̀ |