Quran with Yoruba translation - Surah Ya-Sin ayat 57 - يسٓ - Page - Juz 23
﴿لَهُمۡ فِيهَا فَٰكِهَةٞ وَلَهُم مَّا يَدَّعُونَ ﴾ 
[يسٓ: 57]
﴿لهم فيها فاكهة ولهم ما يدعون﴾ [يسٓ: 57]
| Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Èso wà nínú rẹ̀ fún wọn. Ohun tí wọ́n yóò máa bèèrè fún tún wà fún wọn pẹ̀lú  |