Quran with Yoruba translation - Surah As-saffat ayat 112 - الصَّافَات - Page - Juz 23
﴿وَبَشَّرۡنَٰهُ بِإِسۡحَٰقَ نَبِيّٗا مِّنَ ٱلصَّٰلِحِينَ ﴾
[الصَّافَات: 112]
﴿وبشرناه بإسحاق نبيا من الصالحين﴾ [الصَّافَات: 112]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni A tún fún un ní ìró ìdùnnú (nípa bíbí) ’Ishāƙ, (ó máa jẹ́) Ànábì. (Ó sì máa wà) nínú àwọn ẹni rere |