Quran with Yoruba translation - Surah As-saffat ayat 35 - الصَّافَات - Page - Juz 23
﴿إِنَّهُمۡ كَانُوٓاْ إِذَا قِيلَ لَهُمۡ لَآ إِلَٰهَ إِلَّا ٱللَّهُ يَسۡتَكۡبِرُونَ ﴾
[الصَّافَات: 35]
﴿إنهم كانوا إذا قيل لهم لا إله إلا الله يستكبرون﴾ [الصَّافَات: 35]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú nígbà tí wọ́n bá sọ fún wọn pé "Kò sí ọlọ́hun tí ìjọ́sìn tọ́ sí àfi Allāhu.", wọn yóò máa ṣègbéraga |