Quran with Yoruba translation - Surah As-saffat ayat 37 - الصَّافَات - Page - Juz 23
﴿بَلۡ جَآءَ بِٱلۡحَقِّ وَصَدَّقَ ٱلۡمُرۡسَلِينَ ﴾
[الصَّافَات: 37]
﴿بل جاء بالحق وصدق المرسلين﴾ [الصَّافَات: 37]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Kò rí bẹ́ẹ̀. Ó mú òdodo wá ni. Ó sì ń jẹ́rìí sí òdodo àwọn Òjíṣẹ́ náà |