Quran with Yoruba translation - Surah As-saffat ayat 71 - الصَّافَات - Page - Juz 23
﴿وَلَقَدۡ ضَلَّ قَبۡلَهُمۡ أَكۡثَرُ ٱلۡأَوَّلِينَ ﴾
[الصَّافَات: 71]
﴿ولقد ضل قبلهم أكثر الأولين﴾ [الصَّافَات: 71]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ àwọn ẹni àkọ́kọ́ ti ṣìnà ṣíwájú wọn |