Quran with Yoruba translation - Surah As-saffat ayat 91 - الصَّافَات - Page - Juz 23
﴿فَرَاغَ إِلَىٰٓ ءَالِهَتِهِمۡ فَقَالَ أَلَا تَأۡكُلُونَ ﴾
[الصَّافَات: 91]
﴿فراغ إلى آلهتهم فقال ألا تأكلون﴾ [الصَّافَات: 91]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nígbà náà, ó lọ sí ọ̀dọ̀ àwọn òrìṣà wọn. Ó sì sọ pé: "Ṣé ẹ ò níí jẹun ni |