Quran with Yoruba translation - Surah sad ayat 30 - صٓ - Page - Juz 23
﴿وَوَهَبۡنَا لِدَاوُۥدَ سُلَيۡمَٰنَۚ نِعۡمَ ٱلۡعَبۡدُ إِنَّهُۥٓ أَوَّابٌ ﴾
[صٓ: 30]
﴿ووهبنا لداود سليمان نعم العبد إنه أواب﴾ [صٓ: 30]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni A fi (Ànábì) Sulaemọ̄n ta (Ànábì) Dāwūd lọ́rẹ. Ẹrúsìn rere ni. Dájúdájú olùṣẹ́rí sọ́dọ̀ (Allāhu) ni (nípa ìronúpìwàdà) |