Quran with Yoruba translation - Surah sad ayat 32 - صٓ - Page - Juz 23
﴿فَقَالَ إِنِّيٓ أَحۡبَبۡتُ حُبَّ ٱلۡخَيۡرِ عَن ذِكۡرِ رَبِّي حَتَّىٰ تَوَارَتۡ بِٱلۡحِجَابِ ﴾
[صٓ: 32]
﴿فقال إني أحببت حب الخير عن ذكر ربي حتى توارت بالحجاب﴾ [صٓ: 32]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni ó sọ pé: "Dájúdájú èmi fẹ́ràn ìfẹ́ ohun rere (ìyẹn, àwọn ẹṣin náà) dípò ìrántí Olúwa Mi (ìyẹn, ìrun ‘Asr) títí òòrùn fi wọ̀ |