Quran with Yoruba translation - Surah sad ayat 33 - صٓ - Page - Juz 23
﴿رُدُّوهَا عَلَيَّۖ فَطَفِقَ مَسۡحَۢا بِٱلسُّوقِ وَٱلۡأَعۡنَاقِ ﴾
[صٓ: 33]
﴿ردوها علي فطفق مسحا بالسوق والأعناق﴾ [صٓ: 33]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ẹ dá wọn padà sọ́dọ̀ mi. "Ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í fi idà gé wọn ní ẹsẹ̀ àti ní ọrùn |