Quran with Yoruba translation - Surah sad ayat 5 - صٓ - Page - Juz 23
﴿أَجَعَلَ ٱلۡأٓلِهَةَ إِلَٰهٗا وَٰحِدًاۖ إِنَّ هَٰذَا لَشَيۡءٌ عُجَابٞ ﴾
[صٓ: 5]
﴿أجعل الآلهة إلها واحدا إن هذا لشيء عجاب﴾ [صٓ: 5]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ṣé ó máa sọ àwọn òrìṣà di Ọlọ́hun Ọ̀kan ṣoṣo tí A óò máa jọ́sìn fún ni? Dájúdájú èyí mà ni n̄ǹkan ìyanu |