Quran with Yoruba translation - Surah sad ayat 57 - صٓ - Page - Juz 23
﴿هَٰذَا فَلۡيَذُوقُوهُ حَمِيمٞ وَغَسَّاقٞ ﴾ 
[صٓ: 57]
﴿هذا فليذوقوه حميم وغساق﴾ [صٓ: 57]
| Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Èyí (rí bẹ́ẹ̀). Nítorí náà, kí wọ́n tọ́ ọ wò; omi gbígbóná àti àwọyúnwẹ̀jẹ̀ |