Quran with Yoruba translation - Surah sad ayat 71 - صٓ - Page - Juz 23
﴿إِذۡ قَالَ رَبُّكَ لِلۡمَلَٰٓئِكَةِ إِنِّي خَٰلِقُۢ بَشَرٗا مِّن طِينٖ ﴾
[صٓ: 71]
﴿إذ قال ربك للملائكة إني خالق بشرا من طين﴾ [صٓ: 71]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Rántí) nígbà tí Olúwa rẹ sọ fún àwọn mọlāika pé: "Dájúdájú Èmi yóò dá abara kan láti inú ẹrùpẹ̀ |