Quran with Yoruba translation - Surah sad ayat 72 - صٓ - Page - Juz 23
﴿فَإِذَا سَوَّيۡتُهُۥ وَنَفَخۡتُ فِيهِ مِن رُّوحِي فَقَعُواْ لَهُۥ سَٰجِدِينَ ﴾
[صٓ: 72]
﴿فإذا سويته ونفخت فيه من روحي فقعوا له ساجدين﴾ [صٓ: 72]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nígbà tí Mo bá ṣe é t’ó dọ́gba jálẹ̀ tán, tí Mo sì fẹ́ nínú atẹ́gùn ẹ̀mí tí Mo dá sínú rẹ̀, nígbà náà ẹ dojú bolẹ̀ fún un ní olùforíkanlẹ̀-kíni |