Quran with Yoruba translation - Surah sad ayat 74 - صٓ - Page - Juz 23
﴿إِلَّآ إِبۡلِيسَ ٱسۡتَكۡبَرَ وَكَانَ مِنَ ٱلۡكَٰفِرِينَ ﴾
[صٓ: 74]
﴿إلا إبليس استكبر وكان من الكافرين﴾ [صٓ: 74]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àyàfi ’Iblīs, tí ó ṣègbéraga. Ó sì wà nínú àwọn aláìgbàgbọ́ |