Quran with Yoruba translation - Surah sad ayat 76 - صٓ - Page - Juz 23
﴿قَالَ أَنَا۠ خَيۡرٞ مِّنۡهُ خَلَقۡتَنِي مِن نَّارٖ وَخَلَقۡتَهُۥ مِن طِينٖ ﴾
[صٓ: 76]
﴿قال أنا خير منه خلقتني من نار وخلقته من طين﴾ [صٓ: 76]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ó wí pé: "Èmi lóore jùlọ sí òun; O dá èmi láti ara iná. O sì dá òun láti ara erùpẹ̀ amọ̀ |