Quran with Yoruba translation - Surah Az-Zumar ayat 14 - الزُّمَر - Page - Juz 23
﴿قُلِ ٱللَّهَ أَعۡبُدُ مُخۡلِصٗا لَّهُۥ دِينِي ﴾
[الزُّمَر: 14]
﴿قل الله أعبد مخلصا له ديني﴾ [الزُّمَر: 14]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Sọ pé: "Allāhu ni èmi yóò máa jọ́sìn fún (mo máa jẹ́) olùṣe-àfọ̀mọ́-ẹ̀sìn mi fún Un |