Quran with Yoruba translation - Surah Az-Zumar ayat 37 - الزُّمَر - Page - Juz 24
﴿وَمَن يَهۡدِ ٱللَّهُ فَمَا لَهُۥ مِن مُّضِلٍّۗ أَلَيۡسَ ٱللَّهُ بِعَزِيزٖ ذِي ٱنتِقَامٖ ﴾
[الزُّمَر: 37]
﴿ومن يهد الله فما له من مضل أليس الله بعزيز ذي انتقام﴾ [الزُّمَر: 37]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ẹnikẹ́ni tí Allāhu bá fi mọ̀nà (’Islām), kò lè sí aṣinilọ́nà fún un. Ṣé Allāhu kọ́ ni Alágbára, Olùgba-ẹ̀san |