Quran with Yoruba translation - Surah An-Nisa’ ayat 148 - النِّسَاء - Page - Juz 6
﴿۞ لَّا يُحِبُّ ٱللَّهُ ٱلۡجَهۡرَ بِٱلسُّوٓءِ مِنَ ٱلۡقَوۡلِ إِلَّا مَن ظُلِمَۚ وَكَانَ ٱللَّهُ سَمِيعًا عَلِيمًا ﴾
[النِّسَاء: 148]
﴿لا يحب الله الجهر بالسوء من القول إلا من ظلم وكان الله﴾ [النِّسَاء: 148]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Allāhu kò nífẹ̀ẹ́ sí ariwo èpè ṣíṣẹ́ (láti ọ̀dọ̀ ẹnikẹ́ni) àyàfi ẹni tí wọ́n bá ṣe àbòsí sí. Allāhu sì ń jẹ́ Olùgbọ́, Onímọ̀ |