×

Dajudaju awon t’o n sai gbagbo ninu Allahu ati awon Ojise Re, 4:150 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah An-Nisa’ ⮕ (4:150) ayat 150 in Yoruba

4:150 Surah An-Nisa’ ayat 150 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah An-Nisa’ ayat 150 - النِّسَاء - Page - Juz 6

﴿إِنَّ ٱلَّذِينَ يَكۡفُرُونَ بِٱللَّهِ وَرُسُلِهِۦ وَيُرِيدُونَ أَن يُفَرِّقُواْ بَيۡنَ ٱللَّهِ وَرُسُلِهِۦ وَيَقُولُونَ نُؤۡمِنُ بِبَعۡضٖ وَنَكۡفُرُ بِبَعۡضٖ وَيُرِيدُونَ أَن يَتَّخِذُواْ بَيۡنَ ذَٰلِكَ سَبِيلًا ﴾
[النِّسَاء: 150]

Dajudaju awon t’o n sai gbagbo ninu Allahu ati awon Ojise Re, ti won fe sopinya laaarin Allahu ati awon Ojise Re, ti won si n wi pe: “A gbagbo ninu apa kan, a si sai gbagbo ninu apa kan,” won si fe mu ona kan to (lesin) laaarin iyen

❮ Previous Next ❯

ترجمة: إن الذين يكفرون بالله ورسله ويريدون أن يفرقوا بين الله ورسله ويقولون, باللغة اليوربا

﴿إن الذين يكفرون بالله ورسله ويريدون أن يفرقوا بين الله ورسله ويقولون﴾ [النِّسَاء: 150]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Dájúdájú àwọn t’ó ń ṣàì gbàgbọ́ nínú Allāhu àti àwọn Òjíṣẹ́ Rẹ̀, tí wọ́n fẹ́ ṣòpínyà láààrin Allāhu àti àwọn Òjíṣẹ́ Rẹ̀, tí wọ́n sì ń wí pé: “A gbàgbọ́ nínú apá kan, a sì ṣàì gbàgbọ́ nínú apá kan,” wọ́n sì fẹ́ mú ọ̀nà kan tọ̀ (lẹ́sìn) láààrin ìyẹn
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek