Quran with Yoruba translation - Surah An-Nisa’ ayat 151 - النِّسَاء - Page - Juz 6
﴿أُوْلَٰٓئِكَ هُمُ ٱلۡكَٰفِرُونَ حَقّٗاۚ وَأَعۡتَدۡنَا لِلۡكَٰفِرِينَ عَذَابٗا مُّهِينٗا ﴾
[النِّسَاء: 151]
﴿أولئك هم الكافرون حقا وأعتدنا للكافرين عذابا مهينا﴾ [النِّسَاء: 151]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ní òdodo, àwọn wọ̀nyẹn, àwọn ni aláìgbàgbọ́. A sì ti pèsè Ìyà tí í yẹpẹrẹ ẹ̀dá sílẹ̀ de àwọn aláìgbàgbọ́ |