Quran with Yoruba translation - Surah An-Nisa’ ayat 156 - النِّسَاء - Page - Juz 6
﴿وَبِكُفۡرِهِمۡ وَقَوۡلِهِمۡ عَلَىٰ مَرۡيَمَ بُهۡتَٰنًا عَظِيمٗا ﴾
[النِّسَاء: 156]
﴿وبكفرهم وقولهم على مريم بهتانا عظيما﴾ [النِّسَاء: 156]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àti nítorí àìgbàgbọ́ wọn àti ọ̀rọ̀ wọn lórí Mọryam ní ti ìbànilórúkọjẹ́ t’ó tóbi (Allāhu tún fi èdídí dí ọkàn wọn) |