×

Ati nitori oro won (yii): “Dajudaju awa pa Mosih, ‘Isa omo Moryam, 4:157 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah An-Nisa’ ⮕ (4:157) ayat 157 in Yoruba

4:157 Surah An-Nisa’ ayat 157 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah An-Nisa’ ayat 157 - النِّسَاء - Page - Juz 6

﴿وَقَوۡلِهِمۡ إِنَّا قَتَلۡنَا ٱلۡمَسِيحَ عِيسَى ٱبۡنَ مَرۡيَمَ رَسُولَ ٱللَّهِ وَمَا قَتَلُوهُ وَمَا صَلَبُوهُ وَلَٰكِن شُبِّهَ لَهُمۡۚ وَإِنَّ ٱلَّذِينَ ٱخۡتَلَفُواْ فِيهِ لَفِي شَكّٖ مِّنۡهُۚ مَا لَهُم بِهِۦ مِنۡ عِلۡمٍ إِلَّا ٱتِّبَاعَ ٱلظَّنِّۚ وَمَا قَتَلُوهُ يَقِينَۢا ﴾
[النِّسَاء: 157]

Ati nitori oro won (yii): “Dajudaju awa pa Mosih, ‘Isa omo Moryam, Ojise Allahu.” Won ko pa a, won ko si kan an mo agbelebuu, sugbon A gbe aworan re wo elomiiran fun won ni. Dajudaju awon t’o yapa-enu nipa re, kuku wa ninu iyemeji ninu re; ko si imo kan fun won nipa re afi titele erokero. Won ko pa a ni amodaju. surah ali ‘Imron; 3:7 surah al-’Ani‘am; 6: 99 ati

❮ Previous Next ❯

ترجمة: وقولهم إنا قتلنا المسيح عيسى ابن مريم رسول الله وما قتلوه وما, باللغة اليوربا

﴿وقولهم إنا قتلنا المسيح عيسى ابن مريم رسول الله وما قتلوه وما﴾ [النِّسَاء: 157]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Àti nítorí ọ̀rọ̀ wọn (yìí): “Dájúdájú àwa pa Mọsīh, ‘Īsā ọmọ Mọryam, Òjíṣẹ́ Allāhu.” Wọn kò pa á, wọn kò sì kàn án mọ́ àgbélébùú, ṣùgbọ́n A gbé àwòrán rẹ̀ wọ ẹlòmíìràn fún wọn ni. Dájúdájú àwọn t’ó yapa-ẹnu nípa rẹ̀, kúkú wà nínú iyèméjì nínú rẹ̀; kò sí ìmọ̀ kan fún wọn nípa rẹ̀ àfi títẹ̀lé èròkérò. Wọn kò pa á ní àmọ̀dájú. sūrah āli ‘Imrọ̄n; 3:7 sūrah al-’Ani‘ām; 6: 99 àti
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek