×

Ki ni ipalara ti o maa se fun won ti won ba 4:39 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah An-Nisa’ ⮕ (4:39) ayat 39 in Yoruba

4:39 Surah An-Nisa’ ayat 39 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah An-Nisa’ ayat 39 - النِّسَاء - Page - Juz 5

﴿وَمَاذَا عَلَيۡهِمۡ لَوۡ ءَامَنُواْ بِٱللَّهِ وَٱلۡيَوۡمِ ٱلۡأٓخِرِ وَأَنفَقُواْ مِمَّا رَزَقَهُمُ ٱللَّهُۚ وَكَانَ ٱللَّهُ بِهِمۡ عَلِيمًا ﴾
[النِّسَاء: 39]

Ki ni ipalara ti o maa se fun won ti won ba gbagbo ninu Allahu ati Ojo Ikeyin, ti won si na ninu ohun ti Allahu se ni arisiki fun won? Allahu si je Onimo nipa won

❮ Previous Next ❯

ترجمة: وماذا عليهم لو آمنوا بالله واليوم الآخر وأنفقوا مما رزقهم الله وكان, باللغة اليوربا

﴿وماذا عليهم لو آمنوا بالله واليوم الآخر وأنفقوا مما رزقهم الله وكان﴾ [النِّسَاء: 39]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Kí ni ìpalára tí ó máa ṣe fún wọn tí wọ́n bá gbàgbọ́ nínú Allāhu àti Ọjọ́ Ìkẹyìn, tí wọ́n sì ná nínú ohun tí Allāhu ṣe ní arísìkí fún wọn? Allāhu sì jẹ́ Onímọ̀ nípa wọ́n
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek