Quran with Yoruba translation - Surah An-Nisa’ ayat 53 - النِّسَاء - Page - Juz 5
﴿أَمۡ لَهُمۡ نَصِيبٞ مِّنَ ٱلۡمُلۡكِ فَإِذٗا لَّا يُؤۡتُونَ ٱلنَّاسَ نَقِيرًا ﴾
[النِّسَاء: 53]
﴿أم لهم نصيب من الملك فإذا لا يؤتون الناس نقيرا﴾ [النِّسَاء: 53]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Tàbí ìpín kan ń bẹ fún wọn nínú ìjọba (Wa) ni? Ti ó bá rí bẹ́ẹ̀ wọn kò níí fún àwọn ẹ̀nìyàn ní èékán kóró dàbínú |