Quran with Yoruba translation - Surah An-Nisa’ ayat 55 - النِّسَاء - Page - Juz 5
﴿فَمِنۡهُم مَّنۡ ءَامَنَ بِهِۦ وَمِنۡهُم مَّن صَدَّ عَنۡهُۚ وَكَفَىٰ بِجَهَنَّمَ سَعِيرًا ﴾
[النِّسَاء: 55]
﴿فمنهم من آمن به ومنهم من صد عنه وكفى بجهنم سعيرا﴾ [النِّسَاء: 55]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nítorí náà, ó ń bẹ nínú wọn ẹni t’ó gbàgbọ́ nínú rẹ̀. Ó sì ń bẹ nínú wọn ẹni t’ó ṣẹ́rí kúrò níbẹ̀. Jahanamọ sì tó ní iná t’ó ń jò |