Quran with Yoruba translation - Surah An-Nisa’ ayat 98 - النِّسَاء - Page - Juz 5
﴿إِلَّا ٱلۡمُسۡتَضۡعَفِينَ مِنَ ٱلرِّجَالِ وَٱلنِّسَآءِ وَٱلۡوِلۡدَٰنِ لَا يَسۡتَطِيعُونَ حِيلَةٗ وَلَا يَهۡتَدُونَ سَبِيلٗا ﴾
[النِّسَاء: 98]
﴿إلا المستضعفين من الرجال والنساء والولدان لا يستطيعون حيلة ولا يهتدون سبيلا﴾ [النِّسَاء: 98]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àyàfi àwọn aláìlágbára nínú àwọn ọkùnrin, àwọn obìnrin àti àwọn ọmọdé tí kò ní ìkápá ọgbọ́n kan, tí wọn kò sì dá ọ̀nà mọ̀ (dé ìlú Mọdīnah) |