Quran with Yoruba translation - Surah An-Nisa’ ayat 99 - النِّسَاء - Page - Juz 5
﴿فَأُوْلَٰٓئِكَ عَسَى ٱللَّهُ أَن يَعۡفُوَ عَنۡهُمۡۚ وَكَانَ ٱللَّهُ عَفُوًّا غَفُورٗا ﴾
[النِّسَاء: 99]
﴿فأولئك عسى الله أن يعفو عنهم وكان الله عفوا غفورا﴾ [النِّسَاء: 99]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nítorí náà, àwọn wọ̀nyẹn, ó súnmọ́ kí Allāhu ṣàmójúkúrò fún wọn. Allāhu sì ń jẹ́ Alámòjúúkúrò, Aláforíjìn |