Quran with Yoruba translation - Surah Ghafir ayat 17 - غَافِر - Page - Juz 24
﴿ٱلۡيَوۡمَ تُجۡزَىٰ كُلُّ نَفۡسِۭ بِمَا كَسَبَتۡۚ لَا ظُلۡمَ ٱلۡيَوۡمَۚ إِنَّ ٱللَّهَ سَرِيعُ ٱلۡحِسَابِ ﴾
[غَافِر: 17]
﴿اليوم تجزى كل نفس بما كسبت لا ظلم اليوم إن الله سريع﴾ [غَافِر: 17]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ní òní ni A óò san ẹ̀mí kọ̀ọ̀kan ní ẹ̀san ohun tí ó ṣe níṣẹ́. Kò sì sí àbòsí kan ní òní. Dájúdájú Allāhu ni Olùyára níbi ìṣírò-iṣẹ́ |