Quran with Yoruba translation - Surah Ghafir ayat 63 - غَافِر - Page - Juz 24
﴿كَذَٰلِكَ يُؤۡفَكُ ٱلَّذِينَ كَانُواْ بِـَٔايَٰتِ ٱللَّهِ يَجۡحَدُونَ ﴾
[غَافِر: 63]
﴿كذلك يؤفك الذين كانوا بآيات الله يجحدون﴾ [غَافِر: 63]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Báyẹn náà ni wọ́n ṣe ń ṣẹ́ àwọn t’ó ń tako àwọn āyah Allāhu lórí kúrò níbi òdodo (ṣíwájú tiwọn) |