Quran with Yoruba translation - Surah Ghafir ayat 69 - غَافِر - Page - Juz 24
﴿أَلَمۡ تَرَ إِلَى ٱلَّذِينَ يُجَٰدِلُونَ فِيٓ ءَايَٰتِ ٱللَّهِ أَنَّىٰ يُصۡرَفُونَ ﴾
[غَافِر: 69]
﴿ألم تر إلى الذين يجادلون في آيات الله أنى يصرفون﴾ [غَافِر: 69]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ṣé o ò rí àwọn tí ń ṣàríyànjiyàn nípa àwọn āyah Allāhu bí wọ́n ṣe ń ṣẹ́rí wọn kúrò níbi òdodo |