Quran with Yoruba translation - Surah Fussilat ayat 19 - فُصِّلَت - Page - Juz 24
﴿وَيَوۡمَ يُحۡشَرُ أَعۡدَآءُ ٱللَّهِ إِلَى ٱلنَّارِ فَهُمۡ يُوزَعُونَ ﴾
[فُصِّلَت: 19]
﴿ويوم يحشر أعداء الله إلى النار فهم يوزعون﴾ [فُصِّلَت: 19]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ní ọjọ́ tí wọ́n máa kó àwọn ọ̀tá Allāhu jọ síbi Iná, wọn yó sì kó àwọn ẹni àkọ́kọ́ wọn papọ̀ mọ́ àwọn ẹni ìkẹ́yìn wọn |