Quran with Yoruba translation - Surah Ash-Shura ayat 10 - الشُّوري - Page - Juz 25
﴿وَمَا ٱخۡتَلَفۡتُمۡ فِيهِ مِن شَيۡءٖ فَحُكۡمُهُۥٓ إِلَى ٱللَّهِۚ ذَٰلِكُمُ ٱللَّهُ رَبِّي عَلَيۡهِ تَوَكَّلۡتُ وَإِلَيۡهِ أُنِيبُ ﴾
[الشُّوري: 10]
﴿وما اختلفتم فيه من شيء فحكمه إلى الله ذلكم الله ربي عليه﴾ [الشُّوري: 10]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ohunkóhun tí ẹ bá yapa ẹnu nípa rẹ̀, ìdájọ́ rẹ̀ di ọ̀dọ̀ Allāhu. Ìyẹn ni Allāhu, Olúwa mi. Òun ni mo gbáralé. Ọ̀dọ̀ Rẹ̀ sì ni mo máa ṣẹ́rí padà sí (ní ti ìronúpìwàdà). ọ̀rọ̀ Allāhu àti ìdájọ́ Rẹ̀. Pẹ̀lú àgbọ́yé yìí āyah yìí jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn āyah t’ó ń pa wá láṣẹ láti fi al-Ƙur’an àti sunnah Ànábì (sollalāhu 'alayhi wa sallam) yanjú àwọn ọ̀rọ̀ ìyapa-ẹnu |