Quran with Yoruba translation - Surah Ash-Shura ayat 37 - الشُّوري - Page - Juz 25
﴿وَٱلَّذِينَ يَجۡتَنِبُونَ كَبَٰٓئِرَ ٱلۡإِثۡمِ وَٱلۡفَوَٰحِشَ وَإِذَا مَا غَضِبُواْ هُمۡ يَغۡفِرُونَ ﴾
[الشُّوري: 37]
﴿والذين يجتنبون كبائر الإثم والفواحش وإذا ما غضبوا هم يغفرون﴾ [الشُّوري: 37]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Ohun tí ó wà lọ́dọ̀ Allāhu tún wà fún) àwọn t’ó ń jìnnà sí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ ńláńlá àti àwọn ìwà ìbàjẹ́, àti (àwọn t’ó jẹ́ pé) nígbà tí wọ́n bá bínú, wọ́n yóò ṣàforíjìn |