Quran with Yoruba translation - Surah Az-Zukhruf ayat 15 - الزُّخرُف - Page - Juz 25
﴿وَجَعَلُواْ لَهُۥ مِنۡ عِبَادِهِۦ جُزۡءًاۚ إِنَّ ٱلۡإِنسَٰنَ لَكَفُورٞ مُّبِينٌ ﴾
[الزُّخرُف: 15]
﴿وجعلوا له من عباده جزءا إن الإنسان لكفور مبين﴾ [الزُّخرُف: 15]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọ́n fi ìpín kan nínú àwọn ẹrúsìn (Allāhu) tì sí ọ̀dọ̀ Rẹ̀ (ní ti ọmọ bíbí). Dájúdájú ènìyàn ni aláìmoore pọ́nńbélé |