Quran with Yoruba translation - Surah Az-Zukhruf ayat 3 - الزُّخرُف - Page - Juz 25
﴿إِنَّا جَعَلۡنَٰهُ قُرۡءَٰنًا عَرَبِيّٗا لَّعَلَّكُمۡ تَعۡقِلُونَ ﴾
[الزُّخرُف: 3]
﴿إنا جعلناه قرآنا عربيا لعلكم تعقلون﴾ [الزُّخرُف: 3]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú Àwa sọ ọ́ ní al-Ƙur’ān. (A sì sọ̀ ọ́ kalẹ̀ ní) èdè Lárúbáwá nítorí kí ẹ lè ṣe làákàyè |