Quran with Yoruba translation - Surah Az-Zukhruf ayat 4 - الزُّخرُف - Page - Juz 25
﴿وَإِنَّهُۥ فِيٓ أُمِّ ٱلۡكِتَٰبِ لَدَيۡنَا لَعَلِيٌّ حَكِيمٌ ﴾
[الزُّخرُف: 4]
﴿وإنه في أم الكتاب لدينا لعلي حكيم﴾ [الزُّخرُف: 4]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àti pé dájúdájú nínú Tírà Ìpìlẹ̀ t’ó wà lọ́dọ̀ Wa, al-Ƙur’ān ga, ó kún fún ọgbọ́n |