Quran with Yoruba translation - Surah Az-Zukhruf ayat 34 - الزُّخرُف - Page - Juz 25
﴿وَلِبُيُوتِهِمۡ أَبۡوَٰبٗا وَسُرُرًا عَلَيۡهَا يَتَّكِـُٔونَ ﴾
[الزُّخرُف: 34]
﴿ولبيوتهم أبوابا وسررا عليها يتكئون﴾ [الزُّخرُف: 34]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (A ìbá tún ṣe) àwọn ẹnu ọ̀nà ilé wọn àti àwọn ibùsùn tí wọn yóò máa rọ̀gbọ̀kú lé lórí (ní fàdákà) |