Quran with Yoruba translation - Surah Az-Zukhruf ayat 41 - الزُّخرُف - Page - Juz 25
﴿فَإِمَّا نَذۡهَبَنَّ بِكَ فَإِنَّا مِنۡهُم مُّنتَقِمُونَ ﴾
[الزُّخرُف: 41]
﴿فإما نذهبن بك فإنا منهم منتقمون﴾ [الزُّخرُف: 41]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nítorí náà, ó ṣeé ṣe kí Á ti mú ọ kúrò (lórí ilẹ̀ ayé ṣíwájú àsìkò ìyà wọn), dájúdájú Àwa yóò gbẹ̀san (ìyà) lára wọn |