Quran with Yoruba translation - Surah Ad-Dukhan ayat 28 - الدُّخان - Page - Juz 25
﴿كَذَٰلِكَۖ وَأَوۡرَثۡنَٰهَا قَوۡمًا ءَاخَرِينَ ﴾
[الدُّخان: 28]
﴿كذلك وأورثناها قوما آخرين﴾ [الدُّخان: 28]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Báyẹn (ni ọ̀rọ̀ wọn ṣe rí). A sì jogún (ìlú) wọ́n fún ìjọ ènìyàn mìíràn |