Quran with Yoruba translation - Surah Ad-Dukhan ayat 33 - الدُّخان - Page - Juz 25
﴿وَءَاتَيۡنَٰهُم مِّنَ ٱلۡأٓيَٰتِ مَا فِيهِ بَلَٰٓؤٞاْ مُّبِينٌ ﴾
[الدُّخان: 33]
﴿وآتيناهم من الآيات ما فيه بلاء مبين﴾ [الدُّخان: 33]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni A sì fún wọn ní àwọn àmì tí àdánwò pọ́nńbélé wà nínú rẹ̀ |