Quran with Yoruba translation - Surah Al-Jathiyah ayat 36 - الجاثِية - Page - Juz 25
﴿فَلِلَّهِ ٱلۡحَمۡدُ رَبِّ ٱلسَّمَٰوَٰتِ وَرَبِّ ٱلۡأَرۡضِ رَبِّ ٱلۡعَٰلَمِينَ ﴾
[الجاثِية: 36]
﴿فلله الحمد رب السموات ورب الأرض رب العالمين﴾ [الجاثِية: 36]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nítorí náà, gbogbo ọpẹ́ ń jẹ́ ti Allāhu, Olúwa àwọn sánmọ̀ àti ilẹ̀, Olúwa gbogbo ẹ̀dá |