×

(Ranti) nigba ti awon t’o sai gbagbo ko igbonara sinu okan won 48:26 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Al-Fath ⮕ (48:26) ayat 26 in Yoruba

48:26 Surah Al-Fath ayat 26 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Al-Fath ayat 26 - الفَتح - Page - Juz 26

﴿إِذۡ جَعَلَ ٱلَّذِينَ كَفَرُواْ فِي قُلُوبِهِمُ ٱلۡحَمِيَّةَ حَمِيَّةَ ٱلۡجَٰهِلِيَّةِ فَأَنزَلَ ٱللَّهُ سَكِينَتَهُۥ عَلَىٰ رَسُولِهِۦ وَعَلَى ٱلۡمُؤۡمِنِينَ وَأَلۡزَمَهُمۡ كَلِمَةَ ٱلتَّقۡوَىٰ وَكَانُوٓاْ أَحَقَّ بِهَا وَأَهۡلَهَاۚ وَكَانَ ٱللَّهُ بِكُلِّ شَيۡءٍ عَلِيمٗا ﴾
[الفَتح: 26]

(Ranti) nigba ti awon t’o sai gbagbo ko igbonara sinu okan won ni igbonara ti igba aimokan, Allahu si so ifokanbale kale fun Ojise Re ati awon onigbagbo ododo. O si je ki oro iberu (Re) wa pelu won; Won ni eto si i julo, awon ni won si ni in. Allahu si ni Onimo nipa gbogbo nnkan

❮ Previous Next ❯

ترجمة: إذ جعل الذين كفروا في قلوبهم الحمية حمية الجاهلية فأنـزل الله سكينته, باللغة اليوربا

﴿إذ جعل الذين كفروا في قلوبهم الحمية حمية الجاهلية فأنـزل الله سكينته﴾ [الفَتح: 26]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
(Rántí) nígbà tí àwọn t’ó ṣàì gbàgbọ́ kó ìgbónára sínú ọkàn wọn ní ìgbónára ti ìgbà àìmọ̀kan, Allāhu sì sọ ìfọ̀kànbalẹ̀ kalẹ̀ fún Òjíṣẹ́ Rẹ̀ àti àwọn onígbàgbọ́ òdodo. Ó sì jẹ́ kí ọ̀rọ̀ ìbẹ̀rù (Rẹ̀) wà pẹ̀lú wọn; Wọ́n ní ẹ̀tọ́ sí i jùlọ, àwọn ni wọ́n sì ni ín. Allāhu sì ni Onímọ̀ nípa gbogbo n̄ǹkan
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek