Quran with Yoruba translation - Surah Al-Ma’idah ayat 26 - المَائدة - Page - Juz 6
﴿قَالَ فَإِنَّهَا مُحَرَّمَةٌ عَلَيۡهِمۡۛ أَرۡبَعِينَ سَنَةٗۛ يَتِيهُونَ فِي ٱلۡأَرۡضِۚ فَلَا تَأۡسَ عَلَى ٱلۡقَوۡمِ ٱلۡفَٰسِقِينَ ﴾
[المَائدة: 26]
﴿قال فإنها محرمة عليهم أربعين سنة يتيهون في الأرض فلا تأس على﴾ [المَائدة: 26]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Allāhu) sọ pé: “Dájúdájú ó ti di èèwọ̀ fún wọn (láti wọ inú ìlú náà) fún ogójì ọdún tí wọn yóò fi máa rìn rìn rìn lórí ilẹ̀. Nítorí náà, má ṣe banújẹ́ nítorí ìjọ òbìlẹ̀jẹ́.” |