Quran with Yoruba translation - Surah Adh-Dhariyat ayat 15 - الذَّاريَات - Page - Juz 26
﴿إِنَّ ٱلۡمُتَّقِينَ فِي جَنَّٰتٖ وَعُيُونٍ ﴾
[الذَّاريَات: 15]
﴿إن المتقين في جنات وعيون﴾ [الذَّاريَات: 15]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú àwọn olùbẹ̀rù (Allāhu) yóò wà nínú àwọn Ọgbà Ìdẹ̀ra pẹ̀lú àwọn omi odò (ní ìsàlẹ̀ rẹ̀) |