Quran with Yoruba translation - Surah Adh-Dhariyat ayat 16 - الذَّاريَات - Page - Juz 26
﴿ءَاخِذِينَ مَآ ءَاتَىٰهُمۡ رَبُّهُمۡۚ إِنَّهُمۡ كَانُواْ قَبۡلَ ذَٰلِكَ مُحۡسِنِينَ ﴾
[الذَّاريَات: 16]
﴿آخذين ما آتاهم ربهم إنهم كانوا قبل ذلك محسنين﴾ [الذَّاريَات: 16]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọn yóò máa gba n̄ǹkan tí Olúwa wọn bá fún wọn. Dájúdájú wọ́n ti jẹ́ olùṣe-rere ṣíwájú ìyẹn |