Quran with Yoruba translation - Surah Adh-Dhariyat ayat 14 - الذَّاريَات - Page - Juz 26
﴿ذُوقُواْ فِتۡنَتَكُمۡ هَٰذَا ٱلَّذِي كُنتُم بِهِۦ تَسۡتَعۡجِلُونَ ﴾
[الذَّاريَات: 14]
﴿ذوقوا فتنتكم هذا الذي كنتم به تستعجلون﴾ [الذَّاريَات: 14]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ẹ tọ́ ìyà yín wò. Èyí ni n̄ǹkan tí ẹ ti ń wá pẹ̀lú ìkánjú |