Quran with Yoruba translation - Surah Adh-Dhariyat ayat 31 - الذَّاريَات - Page - Juz 27
﴿۞ قَالَ فَمَا خَطۡبُكُمۡ أَيُّهَا ٱلۡمُرۡسَلُونَ ﴾
[الذَّاريَات: 31]
﴿قال فما خطبكم أيها المرسلون﴾ [الذَّاريَات: 31]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Ànábì ’Ibrọ̄hīm) sọ pé: "Kí tún ni ọ̀rọ̀ tí ẹ bá wá, ẹ̀yin Òjíṣẹ́ |